Claim: A Facebook user posted a photo of a car wash with the Sierra Leone flag, saying it is a local car wash in Sierra Leone. Verdict: False. The image is AI-generated and not from any real car wash in Sierra Leone. Full text: A Facebook user named Biggy Smalls posted an image of a …
Àwòrán atẹyinwa ni àwòrán akalekako yii to ṣ’afihan ìkọlù ni ipinle Kwara
Aheso: Atẹjade ikanni X gbe ahesọ pe ile-ise ọmọogun òfurufú ti orile ede Naijiria se ìkọlù si ilu kan ni ipinle Kwara ni àìmọye ìgbà. Abajade iwadii: Asinilona! Iwadii DUBAWA f’ihan pe àwòrán akalekako ọ̀ún kò tọka si ìkọlù òfurufú ni ilu Oke-Ode ti Ipinle Kwara. A rii wipe ipinle Borno ni wọn ti ya …




