Àhesọ: Asare Obedi pín fọ́nrọ́n kan lórí Facebook, èyí tí ó ṣàfihan obìnrin kan tó ń gun òkùn láti sọdá odò. Asare wípé báyìí ló ṣe ń ṣẹlẹ̀ ni Nàìjíríà. Àbájáde Ìwádìí: Irọ́ lèyìí. Ìwádìí DUBAWA ṣàfihàn pé ìlú Sùdánì (Sudan) ni wọ́n ti ya fọ́rọ́n yìí. Ìròyìn Lẹ́kùńrẹ́rẹ́ Aṣàmúlò Facebook kan, Asare Obedi pín …
Apps, pimps and algorithms: How technology is advancing Nigeria’s digital sex trade
She sat at the edge of a bar stool, tired eyes scanning the busy bar in Mokola, Ibadan, Oyo State, in South-West Nigeria. The sound of Afrobeats filled the air,…