Àhesọ: Aṣàmúlò Facebook kan, @Onyee Arangee, sọ wípé Ààrẹ orílẹ-èdè Amẹ́ríkà Donald Trump fẹ́ lọ́wọ́ sí ìdìbò Nàìjíríà tó ń bọ̀ lọ́nà, àti pé ó ti ṣè’lérí láti ríi dájú pé Ààrẹ Bola Tinubu kò tún wọlé lẹ́ẹ̀kejì. Àbájáde Ìwádìí: Irọ́ ni! Kò sí ẹ̀rí àrídájú pé Ààrẹ orílẹ-èdè Amẹ́ríkà sọ ọ̀rọ̀ yìí tàbí fì’fẹ́hàn …
Òye àtọwọ́dá ni wọn fi ṣ’ẹda àwọn fọnran akalekako ori ikanni TikTok wọnyi ti o ṣ’eleri owó iranwọ
Ahesọ: Àwọn fonran kan gbode kan lori ikanni TikTok, ede abinibi Hausa ati Yoruba ni wọn fi se, àwọn eniyan ti o n soro nibe seleri owo iranwo fun àwọn…