Àhesọ: Koiki Media tẹ àtẹ̀jáde kan wípé àwọn orílẹ̀-èdè l’ágbàáyé ti ń gbẹ́sẹ̀lé ìwé ìrìnnà orílẹ-èdè Nàìjíríà. Bákannáà, ó wípé ìwé ìrìnnà ilẹ̀ Yorùbá ti ń fún àwọn ènìyàn láánfàní láti rìnrìn àjò jákèjádò Iwọ̀-oòrun Áfíríkà, Yúróópù, àti Àríwá Amẹ́ríkà. Àbájáde Ìwádìí: Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àhesọ nípa ìdíwọ́ ìwé ìrìnà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣini …
Video portraying ADC campaign not linked to Nigeria
Claim: A social media page shared a video claiming it was shot during a campaign rally of the African Democratic Congress (ADC) political party in Nigeria. Verdict: Misleading! Contrary to…