Láípẹ̀ yii, olumulo ikanni Facebook, From Quarks to Quasars, sọ wipe ara eniyan ni ọkàn keji, isalẹ ẹsẹ̀ lo si wà. “O ni ọkàn keji, o wa ninu iṣan ẹsẹ̀ rẹ,” olumulo ikanni ibaraenisọrọ yii lo sọ eyi. Olumulo naa f’ikun wípé ọkàn keji yii ni iṣan soleus ti o maa n gbe ẹ̀jẹ̀ lati …
Viral rope-crossing video not from Nigeria
Claim: A Facebook user, Asare Obed, shared a video of a woman crossing a river with a rope, claiming the video is from Nigeria. Verdict: False. DUBAWA’s findings reveal that…