Àhesọ: Aṣàmúlò X kan sọ pé ìdá àádọ́rin nínú ọgọ́rùn-ún (70 per cent) àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni kò le kà’wé. Àbájáde Ìwádìí: Irọ́! Dátà láti ẹ̀ka ètò ẹkọ àpapọ̀ (Ministry of Education) fi ìṣirò iye àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí kò le kà’wé sí ìdá-kànlélọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn-ún (31 per cent). Ìròyìn Lẹ́kùńrẹ́rẹ́ Nínú ìjà …
Must candidates be registered voters in constituencies they seek to represent?
Claim: A Facebook user has alleged that a candidate vying for election must be a registered voter of the constituency they seek to represent. Verdict: False! Research conducted by DUBAWA…