Aheso: Olùmúlò Instagram kan, @Drbelswelness, sọ pé ìwádìí tuntun fihàn pé àbùkù kìí débá ẹyin obìnrin pẹ̀lú ọjọ́-orí, àti pé bi okunrin ṣe n dagba sii, bee ni aleebu àtọ̀ rẹ̀ n pọ si. Àbajade iwadii: Aṣinílọ́nà. Ẹ̀rí tí ìmọ̀-jìnlẹ̀ fihàn pé ati àtọ̀ ọkùnrin àti eyin obìnrin ni abuku maa n deba bi won …




