Àhesọ: Nàìjíríà jẹ́ orílẹ̀-èdè kejì tó ní iye ènìyàn tó pọ̀ jùlọ, tí ń gbé pẹ̀lú HIV. Àbájáde Ìwádìí: Ìṣìnà. Ìjábọ̀ ọdún 2018 láti ọwọ́ UNICEF tí ó dá lórí àkójọfáyẹ̀wò ọdún 2015 ní eni náa tọ́ka sí. Èyí kì í ṣe aṣojú tí ó dára jùlọ fún ipò HIV lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Nàìjíríà. Ìròyìn náà …