Orilẹ-ède ẹ́gíptì ni ọrọ ajé rẹ̀ tobi julọ ni ilẹ̀ Áfríkà, kìíse Nàìjíríà

Aheso: Àwọn olumulo ìkànnì ibaraẹnisọrẹ Facebook sọ wípé ọrọ ajé orilẹ-ède Nàìjíríà lo tóbi jùlọ ni ilẹ̀ Áfríkà. Àbájáde ìwádìí: Irọ ni. Iroyin orí ẹrọ alatagba ṣ’àfihàn pé ìlú ẹ́gíptì ni ọrọ ajé re tóbi jùlọ laarin odún 2023 sì 2024, orilẹ-ède Nàìjíríà sì jẹ ipò kẹta ní ilẹ̀ Áfríkà.  Ẹkunrẹrẹ àlàyé  Àwọn àtúnṣe kọọkan … 

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.