Ṣé lóòtọ́ ni pé Trump tí fòfindènà ìwé ìrìnnà titun f’áwọn ọmọ Nàìjíríà?

Àhesọ: Aṣàmúlò TikTok kan, nípasẹ̀ fọ́nrán kan sọ pé Donald Trump ti pàṣe ìdíwọ́ ìwé-ìrìnà fún àwọn aṣíkiri láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ sí US. Àbájáde Ìwádìí: Ìwádìí DUBAWA fi hàn pé wọ́n tí fí ẹ̀rọ́ ayélujára yí fọ́nrán yìí padà láti jọ ohun tí ó ṣẹlẹ̀ lótìítọ́. Bákannáà, ó ṣì di oṣù àkọ́kọ́, ọdún 2025 … 

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.