Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó kọ́ ló wà nínú fónrán akalekako yíì

Ahesọ: Fọ́nrán kan tí àwọn èèyàn pin káàkiri èrò alatagba ṣ’àfihàn arákùnrin kan to n ṣe àríyànjiyàn pelu arabinrin kan ni ilu London. Àwọn olumulo ikanni abẹyẹfo gbé ahesọ pé gómìnà ìpínlè Ondó, Arákùnrin Lucky Aitedayiwa ni ọkùnrin inu fónrán naa.  Abajade ìwádìí: Irọ ni. Biotilẹjẹpe okunrin ti a ri nínù fónrán naa fi ojú … 

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.