Ọmọ Nàìjíríà kọ́ làwọn ọkùnrin tó ń f’àdá bẹ́’rawọn nínu fọ́nrán

Àhesọ: Aṣàmúlò Facebook kan pín fídíò okùnrin méjì tó wọ̀’yá ìjà pẹlú àdá nílùú India. Aṣàmúlò ọ̀hún wípé ọmọ íbò l’àwọn méjèèjì, wọ́n sì ń jà lórí ẹni tí yóò dárí agbègbè tí wọ́n ti ń tá oògùn olóró. Àbájáde Ìwádìí: Ìwádìí fi hàn pé fọ́nrán yìí ṣi ni lọ́nà. Ẹ̀rí inú ìwé ìròyìn ṣàlàyé … 

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.