Ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́: Nínu igbohunsafẹfẹ kan tí àwọn èèyàn ṣ’atunpin lórí ìkànnì WhatsApp, arákùnrin kan kilọ fun àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pé ki wọ́n yàgò fún lílo òògùn Septrin nítorí ó lè mú kí awọ ara ṣí dànù. Àbájáde ìwádìí: Òdodo ni ọ̀rọ̀ náà. Ọkan lára àwọn àpẹẹrẹ tàbí ìpalára lílo oògùn Septrin ni àwọn oloyinbo …
Discover more from HOT SOURCE NEWS
Subscribe to get the latest posts sent to your email.