Kòsí eri to daju pé a le fi ewe ọ̀pẹ òyìnbó dẹkùn ìgbẹ́ ọ̀rìn

Aheso: Olumulo ikanni ibaraẹnisọrẹ Facebook salaye pé a le fi omí latara ewe opeyinbo ṣe ìtọjú ààrùn ìgbẹ́ ọ̀rìn. Àbájáde ìwádìí: Ko sì ẹri to daju nínú ìmọ̀ sáyẹ́nsì pé a le fi ewé opẹyinbo wo ààrùn ìgbẹ́ ọ̀rìn. Àwọn onímọ̀ sọ fún oniwadii wa pé, ó ṣe pàtàkì kí aláìsàn lo òògùn ORS, èyí … 

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.