Aheso: Olumulo ikanni abeyefo, X, salaye pé kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí lè tètè dàgbà sí ojú ara obìnrin tí wọn kò dábẹ́ fún. Àbájáde ìwádìí: Aheso lasan ni oro naa pe kòkòrò afàìsàn àìlèfojúrí lè tètè dàgbà si ojú ara àwọn obinrin ti wón kò kola fún àti wípé ko sì ẹri to daju ninu imo …
Discover more from HOT SOURCE NEWS
Subscribe to get the latest posts sent to your email.