Àhèsọ: Wida’du Rosul Islamic Foundation pín fọ́nrán kan lójú òpó Facebook wípẹlú àhesọ pé ewé mọ̀ríńgà le wo àìsàn ìtọ̀ súgà àti ẹ̀jẹ̀ ríru. Àbájáde: Ìwádìí ìmọ́ sáyẹ́nsì pẹ̀lú ọ̀rọ̀ láti ẹnu àwọn oníṣègùn òyìnbó fihán pé, lótìítọ́, ewé mọ̀ríńgà ní àwọn èròjà tó lè ṣe ìtọ́jú àìsàn ìtọ̀ súgà àti ẹ̀jẹ̀ ríru. Sùgbọ́n, kò …
Discover more from HOT SOURCE NEWS
Subscribe to get the latest posts sent to your email.