Ahesọ: Àwọn fonran kan gbode kan lori ikanni TikTok, ede abinibi Hausa ati Yoruba ni wọn fi se, àwọn eniyan ti o n soro nibe seleri owo iranwo fun àwọn olumulo ikanni naa ti won ba te àwọn linki kookan. Abajade iwadii: Asinilona! Òye atọwọda ni wọn fi ṣ’ẹda àwọn fọnran ọ̀ún, o si ṣeeṣe …
Ǹjẹ́ Trump ṣèlérí láti dènà ìdìbòyan Tinubu l’ọ́dun 2027?
Àhesọ: Aṣàmúlò Facebook kan, @Onyee Arangee, sọ wípé Ààrẹ orílẹ-èdè Amẹ́ríkà Donald Trump fẹ́ lọ́wọ́ sí ìdìbò Nàìjíríà tó ń bọ̀ lọ́nà, àti pé ó ti ṣè’lérí láti ríi dájú…