Ekunrere alaye Osu kewa lodoodun ni ayajo jẹjẹrẹ ọmú lagbaye. Lori gbogbo ẹ̀rọ alatagba, ni oju-ona ati beebeelo, a maa ri àwọ̀ pupa rẹ́súrẹ́sú ti o tọkasi ìṣọ̀kan, ìmọ̀ ati ìrètí. Osu owaara je ayajo jẹjẹrẹ ọmú lagbaye. Oṣù yii ni àwọn egbe kọọkan a bere sii se iwode lati kọni l’ẹkọ nipa jẹjẹrẹ ti …


