Àhesọ: Olumulo ikanni ibaraenisore Facebook so wipe arakunrin Adedeji Adeleke ti kọ lakọ pari ileeṣẹ amunawa re kan ti iye re to bilionu meji owo dọ́là. Abajade iwadii: Irọ ni. Kò sí ojulowo iroyin to ṣ’atilẹyin ahesọ naa. Koda, ileeṣẹ Pacific Holdings, ti ogbeni Adeleke je oludari rẹ̀, kò fi iroyin kankan si ita lori …
Fact-checking : l’innovation au coeur de la bourse 2025 CJID
Le Centre for Journalism Innovation and Development (CJID) franchit une nouvelle étape en matière de lutte contre la désinformation en Afrique francophone. Pour la première fois, une bourse de trois…