Laipẹ yii, ààre Bọla Tinubu kí àwọn ọmọ Nàìjíríà ku àmójubà ọdún tuntun biotilẹjẹpe àwọn ara ilu n kerora eto oro aje ti ijoba rẹ̀ gbekale. Àjo to n risi onka lorilẹede Nàìjíríà(NBS) salaye pe ọ̀wọ́ngógó oun èlò ti lọ soke si. Si bẹẹ, àwọn osiṣẹ́ ijọba ò tíì bẹẹrẹ síí gba gbẹndeke owo oṣù …